ORÍKÌ YÀMMI ÒSÒRÓNGÀ
A Mãe Ancestral Universal
01 Okiti Kata, Ekùn A Pa Eran Má Ni Yan Olu Gbongbo Ki Osun Ebi Ejè Gosun-gosun On Wo Ewu Ejè Ko Pá Eni Ko Je Oka Odun A Ni Esin O Ni Kange Odo Bara Oto lu Omi a Dake Je Pa Eni Omo Opara Oga Ndanu, Sese Iba o ! Iba Ìyàmì o ! NiMo Mo Je Ni Ko Je Ti Aruní Emi Wa Foribale Fun Sese Olu idu Pe O papa Ele Adie Ko Tuka IyaTemi Mi Ni Bariba Li Akoko Emi Ako Ni Ala Mo Le Gbe Agada Emi A Wa Kiyà Onile Ki Ile. Ìbà Ìyàmì o ! Asé O !
02 Ilè mopue o ! Ìyàmì Òsòróngà Mopue o ! Òdu-Logboje Ibá o ! Ibá Òsa-iyeku kibí odu Ìyàmì Òsòróngà Mojubá Obinrin Lode Olo Gèlèdè Ibà Ìyàmì o ! Ohun abáwi fun Agbà Ni agbà Ngbo Ohun awí fun Agbà Ni agbà Ngbá Ohun timowí loníjé osé Ohun mofé kose loní Je kori be e Ní orunkò éhiyn Ìyàmì Òsòróngà Olo hun Òla ! Olo kun Òla ! Ójó ojú ómó , baféfó Aki gbe pue Òòrúnmìlà Ko gbehun Agbe Asè o !
03 Ibà Ìyàmì o ! Ìyàmì Òsòróngà moki o ! E mapa mi E mapa mi E mapa mi Ibi ério É ki gbe mi lo Ibi ério É kigbe mi lo Ori, ki ifá un Édó, ki irigbin O tutu ki imá méja lalè odo Ibi ério è kigbe mi lo Asè o !
Nenhum comentário:
Postar um comentário